Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Sámúẹ́lì 24:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Áráúnà sì wí pé, “Nítorí kín ni Olúwa mi ọba ṣe tọ ìránṣẹ́ rẹ̀ wá?”Dáfídì sì dáhùn pé, “Láti ra ibi ìpakà rẹ lọ́wọ́ rẹ, láti tẹ́ pẹpẹ kan fún Olúwa, kí àrùn ìparun lè dá lára àwọn ènìyàn náà.”

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 24

Wo 2 Sámúẹ́lì 24:21 ni o tọ