Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Sámúẹ́lì 24:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí ańgẹ́lì náà sì nawọ́ rẹ̀ sí Jérúsálẹ́mù láti pa á run, Olúwa sì káàánú nítorí ibi náà, ó sì sọ fún ańgẹ́li tí ń pá àwọn ènìyàn náà run pé, “Ó tó, dá ọwọ́ rẹ dúró wàyìí!” Ańgẹ́lì Olúwa náà sì wà níbi ìpakà Áráúnà ará Jèbúsì.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 24

Wo 2 Sámúẹ́lì 24:16 ni o tọ