Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Sámúẹ́lì 24:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Lọ kí o sì wí fún Dáfídì pé, ‘Bàyìí ni Olúwa wí, èmi fi nǹkan mẹ́ta lọ̀ ọ́; yan ọ̀kan nínú wọn, kí èmi ó sì ṣe é sí ọ.’ ”

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 24

Wo 2 Sámúẹ́lì 24:12 ni o tọ