Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Sámúẹ́lì 23:30-39 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

30. Bénáyà ará Pírátónì,Hídáyì tí àfonífojì.

31. Ábíálíbónì ará Áríbà,Ásámífétì Báríhúmítì;

32. Élíáhíbà ará Sáálíbónì,Jáṣénì Gísónítì,Jónátanì;

33. Ṣámà ará Hárárì,Áhíámù ọmọ Ṣárárì ará Hárárì;

34. Élífélétì ọmọ Áhásibáyì, ọmọ ará Máákíhà,Élíámù ọmọ Áhítófélì ará Gílónì;

35. Hésiráì ará Kérímélì,Páárì ará Áríbà;

36. Ígálì ọmọ Nátanì ti Sóbà,Bánì ará Gádì;

37. Sélékì ará Ámónì,Náhárì ará Béérótì, ẹni tí ń ru ìhámọ́ra Jóábù ọmọ Sérúíà;

38. Írà ará Játírì,Gárébù ará Játírì.

39. Ùráyà ará Hítì.Gbogbo wọn jẹ́ mẹ́tadínlógójì.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 23