Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Sámúẹ́lì 22:50-51 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

50. Nítorí náà èmi ó fi ọpẹ́ fún ọ, Olúwa,láàrin àwọn àjèjì orílẹ̀-èdè: èmi ó sì kọrin sí orúkọ rẹ.

51. Òun ni ilé-ìṣọ́ ìgbàlà fún ọba rẹ̀;ó sì fi àánú hàn fún ẹni-àmì-òróró rẹ̀,fún Dáfídì, àti fún irú-ọmọ rẹ̀ títí láéláé.”

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 22