Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Sámúẹ́lì 22:45-47 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

45. Àwọn àlejò wá láti tẹríba fún mi;bí wọ́n bá ti gbúròó mi, wọn á sì gbọ́ tèmi.

46. Àyà yóò pá àwọn àlejò,wọn ó sì fi ìbẹ̀rù sá kúrò níbi kọ́lọ́fín wọn.

47. “Olúwa ń bẹ́; olùbùkún sì ni àpáta mi!Gbígbéga sì ni Ọlọ́run àpáta ìgbàlà mi.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 22