Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Sámúẹ́lì 22:43 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni èmi sì gún wọn wẹ́wẹ́ bí erùpẹ̀ ilẹ̀,èmi sì tẹ̀ wọ́n mọ́lẹ̀ bí ẹrẹ̀ ìta, èmi sì tẹ́ wọn gbọrọ.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 22

Wo 2 Sámúẹ́lì 22:43 ni o tọ