Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Sámúẹ́lì 21:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìjà kan sì tún wà ní Gátì, ọkùnrin kan sì wà tí ó ga púpọ̀, ó sì ní ìka mẹ́fà ní ọwọ́ kan, àti ọmọ ẹṣẹ̀ mẹ́fà ní ẹṣẹ̀ kan, àpapọ̀ rẹ̀ sì jẹ́ mẹ́rìnlélógún; a sì bí òun náà ní òmìrán.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 21

Wo 2 Sámúẹ́lì 21:20 ni o tọ