Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Sámúẹ́lì 20:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ọmọkùnrin Jóábù sì jáde tọ̀ ọ́ lọ, àti àwọn Kérétì, àti àwọn Pélétì, àti gbogbo àwọn ọkùnrin alágbára: wọ́n sì ti Jérúsálẹ́mù jáde lọ, láti lépa Ṣábà ọmọ Bíkírì.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 20

Wo 2 Sámúẹ́lì 20:7 ni o tọ