Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Sámúẹ́lì 20:24-26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

24. Ádórámù sì jẹ́ olórí àwọn agbowó òde: Jéhóṣáfátì ọmọ Áhílúdì sì jẹ́ olùkọsílẹ̀ ohun tí ó ń ṣẹlẹ̀ ní ìlú.

25. Ṣéfà sì jẹ́ akọ̀wé: Sádókù àti Ábíátarì sì ni àwọn àlùfáà.

26. Írà pẹ̀lú, ará Jáírì ni ń ṣe àlùfáà lọ́dọ̀ Dáfídì.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 20