Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Sámúẹ́lì 20:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọ̀ràn náà kò sì rí bẹ́ẹ̀; ṣùgbọ́n ọkùnrin kan láti òkè Éfúráímù, tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Ṣébà, ọmọ Bíkírì, ni ó gbé ọwọ́ rẹ̀ sòkè sí ọba, àní sí Dáfídì: fi òun nìkanṣoṣo lé wa lọ́wọ́, èmi ó sì fi ìlú sílẹ̀.”Obìnrin náà sì wí fún Jóábù pé, “Wò ó, orí rẹ̀ ni a ó sì sọ láti inú odì wá.”

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 20

Wo 2 Sámúẹ́lì 20:21 ni o tọ