Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Sámúẹ́lì 20:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo àwọn ọkùnrin Ísírẹ́lì sì lọ kúrò lẹ́yìn Dáfídì, wọ́n sì ń tọ́ Ṣébà ọmọ Bíkírì lẹ́yìn: ṣùgbọ́n àwọn ọkùnrin Júdà sì fi ara mọ́ ọba wọn láti odò Jódánì wá títí ó fi dé Jérúsálẹ́mù.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 20

Wo 2 Sámúẹ́lì 20:2 ni o tọ