Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Sámúẹ́lì 20:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n wá, wọ́n sì dó tì í ní Ábélì tí Bẹti Máákà, wọ́n sì mọ odí ti ìlú náà, odi náà sì dúró ti odi ìlú náà, gbogbo ènìyàn tí ń bẹ lọ́dọ̀ Jóábù sì ń gbìyànjú láti wó ògiri náà lulẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 20

Wo 2 Sámúẹ́lì 20:15 ni o tọ