Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Sámúẹ́lì 20:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ámásà sì ń yíràá nínú ẹ̀jẹ̀ láàrin ọ̀nà. Ọkùnrin náà sì ríi pé gbogbo ènìyàn sì dúró tì í, ó sì gbé Ámásà kúrò lójú ọ̀nà lọ sínú ìgbẹ́, ó sì fi aṣọ bò ó, nígbà tí ó rí i pé ẹnìkẹ́ni tí ó bá dé ọ̀dọ̀ rẹ̀, á dúró.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 20

Wo 2 Sámúẹ́lì 20:12 ni o tọ