Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Sámúẹ́lì 2:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ábínérì sì pe Jóábù, ó sì bi í léèrè pé, “Idà yóò máa parún títí láéláé bí? Ǹjẹ́ ìwọ kòì tí ì mọ̀ pé yóò korò nikẹyìn? Ǹjẹ́ yóò ha ti pẹ́ tó kí ìwọ tó sọ fún àwọn ènìyàn náà, kí wọ́n dẹ́kun láti máa lépa arákùnrin wọn.”

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 2

Wo 2 Sámúẹ́lì 2:26 ni o tọ