Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Sámúẹ́lì 2:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jóábù ọmọ Sérúíà pẹ̀lú àwọn ọkùnrin Dáfídì jáde lọ láti lọ bá wọn ní adágún Gíbíónì. Ẹgbẹ́ kan sì jókòó ní apá kan adágún, àti ẹgbẹ́ kejì ní apá kejì adágún.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 2

Wo 2 Sámúẹ́lì 2:13 ni o tọ