Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Sámúẹ́lì 2:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Lẹ́yìn àkókò yìí, Dáfídì wádìí lọ́wọ́ Olúwa. Ó sì béèrè pé, “Ṣé èmi lè gòkè lọ sí ọ̀kan lára àwọn ìlú Júdà?” Olúwa sì wí pé, “Gòkè lọ.”Dáfídì sì béèrè pé, “Ní ibo ni kí èmi kí ó lọ?” Olúwa sì dáa lóhùn pé, “Sí Hébúrónì.”

2. Nígbà náà ni Dáfídì gòkè lọ ṣíbẹ̀ pẹ̀lú ìyàwó rẹ̀ méjì Áhínóámù ará Jésérẹ́lì, àti Ábígáílì obìnrin opó Nábálì ti Kámẹ́lì.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 2