Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Sámúẹ́lì 19:41 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sì wò ó, gbogbo àwọn ọkùnrin Ísírẹ́lì sì tọ ọba wá, wọ́n sì wí fún ọba pé, “Èéṣe tí àwọn arákùnrin wa àwọn ọkùnrin Júdà fi jí ọ kúrò, tí wọ́n sì fi mú ọba àti àwọn ará ilé rẹ̀ gòkè odò Jódánì, àti gbogbo àwọn ènìyàn Dáfídì pẹ̀lú rẹ?”

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 19

Wo 2 Sámúẹ́lì 19:41 ni o tọ