Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Sámúẹ́lì 19:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìṣẹ́gun ijọ́ náà sì di ààwẹ̀ fún gbogbo àwọn ènìyàn náà, nítorí àwọn ènìyàn náà gbọ́ ní ijọ́ náà bí inú ọba ti bàjẹ́ nítorí ọmọ rẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 19

Wo 2 Sámúẹ́lì 19:2 ni o tọ