Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Sámúẹ́lì 18:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba sì bi Kúṣì pé, “Àlàáfíà kọ́ Ábúsálómù ọ̀dọ́mọdékùnrin náà wá bí?”Kúṣì sì dáhùn pe, “Kí àwọn ọ̀ta Olúwa mi ọba, àti gbogbo àwọn tí ó dìde sí ọ ní ibi, rí bí ọ̀dọ́mọdékùnrin náà.”

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 18

Wo 2 Sámúẹ́lì 18:32 ni o tọ