Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Sámúẹ́lì 18:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọkùnrin kan sì rí i, ó sì wí fún Jóábù pé, “Wò ó, èmi rí Ábúsálómù so rọ̀ láàrin igi óákù kan.”

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 18

Wo 2 Sámúẹ́lì 18:10 ni o tọ