Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Sámúẹ́lì 17:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Húṣáì sì wí pé, “Ìwọ mọ baba rẹ àti àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ pé alágbára ni wọ́n, wọ́n sì wà ní Kíkorò ọkàn bí àmọ̀tẹ́kùn tí a gbà ní ọmọ ni pápá: baba rẹ sì jẹ́ jagunjagun ọkùnrin kì yóò bá àwọn ènìyàn náà gbé pọ̀ lóru.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 17

Wo 2 Sámúẹ́lì 17:8 ni o tọ