Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Sámúẹ́lì 17:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti oyin, àti òrí-àmọ́, àti àgùntàn, àti wàràǹkàsì màlúù, wá fún Dáfídì àti fún àwọn ènìyàn tí ń bẹ lọ́dọ̀ rẹ̀, láti jẹ: nítorí tí wọ́n wí pé, “Ebi ń pa àwọn ènìyàn, ó sì rẹ̀ wọ́n, òǹgbẹ sì ń gbẹ wọ́n ní ihà.”

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 17

Wo 2 Sámúẹ́lì 17:29 ni o tọ