Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Sámúẹ́lì 17:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí Dáfídì sì wá sí Mahánáímù, Ṣóbì ọmọ Nahásì ti Rábà tí àwọn ọmọ Ámónì, àti Mákírì ọmọ Ámíélì ti Lodebárì, àti Básíláì ará Gílíádì ti Rógélímù.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 17

Wo 2 Sámúẹ́lì 17:27 ni o tọ