Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Sámúẹ́lì 17:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dáfídì sì dìde, àti gbogbo àwọn ènìyàn tí ń bẹ lọ́dọ̀ rẹ̀, wọ́n sì gòkè odò Jódánì: kí ilẹ̀ tó mọ́, ènìyàn kò kù tí kò gòkè odò Jódánì.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 17

Wo 2 Sámúẹ́lì 17:22 ni o tọ