Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Sámúẹ́lì 17:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nítorí náà èmi dámọ̀ràn pé: Kí gbogbo Ísírẹ́lì wọ́jọ pọ̀ sọ́dọ̀ rẹ, láti Dánì títí dé Bééríṣébà, gẹ́gẹ́ bí iyanrìn létí òkun fún ọ̀pọ̀lọpọ̀; àti pé, kí ìwọ tìkárarẹ ó lọ sí ogun náà.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 17

Wo 2 Sámúẹ́lì 17:11 ni o tọ