Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Sámúẹ́lì 14:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ábúsálómù sì dá Jóábù lóhùn pé, “Wò ó, èmi ránṣẹ́ sí ọ, wí pé, ‘Wá níhìn-ín yìí, èmi ó sì rán ọ lọ sọ́dọ̀ ọba, láti béèrè pé, “Kí ni èmi ti Géṣúrì wá si? Ìbá sàn fún mí bí ó ṣe pé èmi wà lọ́hùn-ún ṣíbẹ̀!” ’ Ǹjẹ́ nísinsin yìí jẹ́ kí èmi lọ síwájú ọba bí ó bá sì ṣe ẹ̀bi ń bẹ nínú mi, kí ó pa mí.”

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 14

Wo 2 Sámúẹ́lì 14:32 ni o tọ