Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Sámúẹ́lì 14:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí ó bá sì rẹ́ irun orí rẹ̀ (nítorí pé lọ́dọ̀ọdún ni òun máa ń rẹ́ ẹ. Nígbà tí ó bá wúwo fún un, òun a sì máa rẹ́ ẹ) òun sì wọn irun orí rẹ̀, ó sì jásí igba ṣẹ́kẹ́lì nínú òṣùwọ̀n ọba.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 14

Wo 2 Sámúẹ́lì 14:26 ni o tọ