Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Sámúẹ́lì 14:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì wí pé, “Èmi bẹ̀ ọ́ jẹ́ kí ọba ó rántí Olúwa Ọlọ́run rẹ̀, kí olùgbẹ̀san ẹ̀jẹ̀ má ṣe ní ipá láti ṣe iparun, kí wọn o má bá a pa ọmọ mi!”Òun sì wí pé, “Bí Olúwa ti ń bẹ láàyè ọ̀kan nínú irun orí ọmọ rẹ ki yóò bọ sílẹ̀.”

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 14

Wo 2 Sámúẹ́lì 14:11 ni o tọ