Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Sámúẹ́lì 11:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìránṣẹ́ náà sì wí fún Dáfídì pé, “Nítòótọ́ àwọn ọkùnrin náà lágbára jù wá lọ, wọ́n sì jáde tọ̀ wá wá ní pápá, àwa sì tẹ̀lé wọn títí wọ́n fi dé ẹ̀yìn odi.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 11

Wo 2 Sámúẹ́lì 11:23 ni o tọ