Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Sámúẹ́lì 11:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn ìgbà tí ọdún yípo, ní àkókò ìgbà tí àwọn ọba náà ń jáde ogun, Dáfídì sì rán Jóábù, àti àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ pẹ̀lú rẹ̀, àti gbogbo Ísírẹ́lì; wọ́n sì pa àwọn ọmọ Ámónì, wọ́n sì dó ti Rábà. Dáfídì sì jókòó ní Jérúsálẹ́mù.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 11

Wo 2 Sámúẹ́lì 11:1 ni o tọ