Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Sámúẹ́lì 1:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dáfídì béèrè pé, “Kí ni ó ṣẹlẹ̀?” “Sọ fún mi.”Ó wí pé, “Àwọn ọkùnrin náà sá láti ojú ogun. Ọ̀pọ̀ wọn ṣubú, wọ́n sì kú. Ṣọ́ọ̀lù àti ọmọ rẹ̀ ọkùnrin Jónátanì sì kú pẹ̀lú.”

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 1

Wo 2 Sámúẹ́lì 1:4 ni o tọ