Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 7:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tí àwa bá wí pé, ‘Àwa lọ sí ìlú, ìyàn wà níbẹ̀,’ àwa yóò sì kú. Tí àwa bá dúró níbí, a máa kú, ǹjẹ́ Nísinsìnyí ẹ jẹ́ kí a lọ sí ibùdó ti àwọn ará Síríà kí àwa kí ó sì tẹríba. Bí wọ́n bá dá wa sí, àwa yóò yè, tí wọ́n bá sì pa wá, bẹ́ẹ̀ ni àwa yóò kú.”

Ka pipe ipin 2 Ọba 7

Wo 2 Ọba 7:4 ni o tọ