Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 7:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìjòyè náà ti wí fún ènìyàn Ọlọ́run pé, “Wò ó, kó dà ti Olúwa bá sí fèrèsé ní ọ̀run, ṣé èyí lè ṣẹlẹ̀?” Ènìyàn Ọlọ́run sì ti dáhùn pé, “kìkì ojú rẹ ni ìwọ yóò fi rí i, Ṣùgbọ́n ìwọ kò ní jẹ ọ̀kan kan lára rẹ̀.”

Ka pipe ipin 2 Ọba 7

Wo 2 Ọba 7:19 ni o tọ