Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 7:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba sì dìde ní ùru ó sì wí fún àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ pé, “Èmi yóò ṣọ fún yín ohun tí àwọn ará Ṣíríà tí ṣe fún wa. Wọ́n mọ̀ wí pé ebi ń pa wá; bẹ́ẹ̀ ni wọ́n sì ti kúrò ni ibùdó láti sá pamọ́ sí ẹ̀gbẹ́ ilé, wọ́n rò wí pé, ‘Wọn yóò jáde lóòtọ́, nígbà náà àwa yóò mú wọn ní ààyè àwa yóò yí wọ inú ìlú lọ.’ ”

Ka pipe ipin 2 Ọba 7

Wo 2 Ọba 7:12 ni o tọ