Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 5:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ní gbogbo ọ̀nà, lọ,” ọba Árámù dá a lóhùn pé, “Èmi yóò fi ìwé ránṣẹ́ sí ọba Ísírẹ́lì.” Bẹ́ẹ̀ ni Námánì lọ, ó sì mú pẹ̀lú rẹ̀ talẹ́ńtì fàdákà mẹ́wàá, ẹgbẹ̀ta ìwọ̀n wúrà (6,000) àti ìpàrọ̀ aṣọ mẹ́wàá.

Ka pipe ipin 2 Ọba 5

Wo 2 Ọba 5:5 ni o tọ