Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 5:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Géhásì, ìránṣẹ́ Èlíṣà ènìyàn Ọlọ́run, ó wí fún ara rẹ̀ pé, “Ọ̀gá mi jẹ́ ẹni tí ó rọ̀ lórí Námánì, ará Árámù, nípa pé kò gba ohunkóhun ní ọwọ́ rẹ̀ ohun tí ó mú wá, gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti ń bẹ láàyè, èmi yóò sá tẹ̀lé e èmi yóò sì gba ohun kan ńi ọwọ́ rẹ̀.”

Ka pipe ipin 2 Ọba 5

Wo 2 Ọba 5:20 ni o tọ