Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 4:43 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Báwo ni èmi yóò ṣe gbé èyí ka iwájú àwọn ọgọ́ọ̀rún ènìyàn (100 men)?” Ìránṣẹ́ rẹ̀ béèrè.Ṣùgbọ́n Èlíṣà dá a lóhùn pé, “Gbé e fún àwọn ènìyàn láti jẹ, nítorí èyí ni ohun tí Olúwa sọ: ‘Wọn yóò jẹ yóò sì tún sẹ́kù’ ”

Ka pipe ipin 2 Ọba 4

Wo 2 Ọba 4:43 ni o tọ