Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 4:41 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èlíṣà sì wí pé, “Mú ìyẹ̀fún díẹ̀ wá,” Ó sì fi sínú ìkòkò ó sì wí pé, “Kí ó sì fi fún àwọn ènìyàn láti jẹ.” Kò sì sí ohun tí ó léwu nínú ìkòkò náà.

Ka pipe ipin 2 Ọba 4

Wo 2 Ọba 4:41 ni o tọ