Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 4:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sáré lọ pàdé rẹ̀ kí o sì béèrè lọ́wọ́ rẹ̀, ‘Ṣé o wà dáadáa? Ṣé ọkọ rẹ wà dáadáa? Ṣé ọmọ rẹ wà dáadáa?’ ”Ó wí pé, “Gbogbo nǹkan wà dáadáa.”

Ka pipe ipin 2 Ọba 4

Wo 2 Ọba 4:26 ni o tọ