Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 4:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó pe ọkọ rẹ̀ ó sì wí pé, “Jọ̀wọ́ rán ọ̀kan lára àwọn ìránṣẹ́ rẹ àti kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ kan kí èmi kí ó lè lọ sí ọ̀dọ̀ ènìyàn Ọlọ́run kíákíá kí n sì padà.”

Ka pipe ipin 2 Ọba 4

Wo 2 Ọba 4:22 ni o tọ