Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 4:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì wí fún ìránṣẹ́ rẹ̀ Géhásì pé, “Pe ará Ṣúnémù.” Bẹ́ẹ̀ ni ó sì pè é wá, ó sì dúró níwájú rẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Ọba 4

Wo 2 Ọba 4:12 ni o tọ