Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 4:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìyàwó ọkùnrin kan láti ara ẹgbẹ́ wòlíì sunkún tọ Èlíṣà wá, “Ìránṣẹ́ rẹ ọkọ mi ti kú, ó sì mọ̀ wí pé ó bu ọlá fún Olúwa. Ṣùgbọ́n Nísinsìn yìí onígbèsè rẹ̀ ti ń bọ̀ láti wá kó ọmọ ọkùnrin mi gẹ́gẹ́ bí ẹrú rẹ̀.”

Ka pipe ipin 2 Ọba 4

Wo 2 Ọba 4:1 ni o tọ