Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 25:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní oṣù kèje, bí ó ti lẹ̀ jẹ́ pé, Ísmáélì ọmọ Nétaníáyà, ọmọ Èlísámà, ẹni tí ó jẹ́ ti ẹ̀jẹ̀ ọba, wá pẹ̀lú àwọn ọkùnrin mẹ́wàá ó sì kọlù Gédálíáyà àti pẹ̀lú àwọn ọkùnrin mẹwàá ará Júdà àti àwọn ará káídéà tí ó wà pẹ̀lú rẹ̀ ní Míspà.

Ka pipe ipin 2 Ọba 25

Wo 2 Ọba 25:25 ni o tọ