Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 25:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Níbẹ̀ ní Ríbílà, ní ilẹ̀ Hámátì, ọba sì kọlù wọ́n, bẹ́ẹ̀ ni Júdà lọ sí oko ẹrú, kúrò láti ilé rẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Ọba 25

Wo 2 Ọba 25:21 ni o tọ