Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 25:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nebukadinésárí olórí ẹ̀ṣọ́ Kó lọ sí ìgbékùn gbogbo ènìyàn tí ó kù ní ìlú, àti àwọn Ísánsà àti àwọn tí ó ti lo sí ọ̀dọ̀ ọba Bábílón.

Ka pipe ipin 2 Ọba 25

Wo 2 Ọba 25:11 ni o tọ