Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 21:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní àgbàlá méjèèjì ilé Olúwa, ó sì kọ́ pẹpẹ fún gbogbo àwọn ìrúbọ nínú ilé, ṣe iṣẹ́ àkíyèsí àfọ̀ṣẹ, ó sì bèèrè lọ́wọ́ àwọn òkú àti àwọn oṣó. Ó sì ṣe ọ̀pọ̀ búburú ní ojú Olúwa, ó sì mú un bínú.

Ka pipe ipin 2 Ọba 21

Wo 2 Ọba 21:5 ni o tọ