Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 21:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ámónì jẹ́ ẹni ọdún méjìlélógún nígbà tí ó jọba. Orúkọ bàbá rẹ̀ a sì máa jẹ́ Méṣúlémétì ọmọbìnrin Hárúsì: ó wá láti Jótíbà, ó sì jọba ní Jérúsálẹ́mù fún ọdún méjì.

Ka pipe ipin 2 Ọba 21

Wo 2 Ọba 21:19 ni o tọ