Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 20:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Rántí, Olúwa mi, bí èmi ṣe rìn níwájú rẹ àti pẹ̀lú bí èmi ṣe jẹ́ olóòtọ́ àti pẹ̀lú gbogbo ọkàn ìfọkànsìn mi tí èmi sì ti ṣe ohun tí ó dára níwájú rẹ.” Heṣekáyà sunkún kíkorò.

Ka pipe ipin 2 Ọba 20

Wo 2 Ọba 20:3 ni o tọ