Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 20:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ti àwọn ìsẹ̀lẹ̀ tó kù nípa ìjọba Heṣekáyà, gbogbo ohun tí ó ṣe tan àti bí ó ti ṣe adágún omi àti ọ̀nà omi náà nípa èyí tí ó gbé wá omi sínú ìlú ńlá, ṣé wọn kò kọ wọ́n sínú ìwé ìgbéṣẹ̀ ayé àwọn ọba àwọn Júdà?

Ka pipe ipin 2 Ọba 20

Wo 2 Ọba 20:20 ni o tọ